Ìlò Àkànlò èdè nínú Àwọn Ìwé Ìtàn Àròsọ Ọladẹ̀jọ Òkédìjí

Oladejo Okediji's use of Language in his novels

Jacob Gbenga

PDF
2,99
Amazon iTunes Thalia.de Weltbild.de Hugendubel Bücher.de ebook.de kobo Osiander Google Books Barnes&Noble bol.com Legimi yourbook.shop Kulturkaufhaus
* Affiliatelinks/Werbelinks
Hinweis: Affiliatelinks/Werbelinks
Links auf reinlesen.de sind sogenannte Affiliate-Links. Wenn du auf so einen Affiliate-Link klickst und über diesen Link einkaufst, bekommt reinlesen.de von dem betreffenden Online-Shop oder Anbieter eine Provision. Für dich verändert sich der Preis nicht.

GRIN Verlag img Link Publisher

Geisteswissenschaften, Kunst, Musik / Allgemeine und Vergleichende Literaturwissenschaft

Beschreibung

Bachelor Thesis from the year 2017 in the subject Literature - Basics, grade: 83.2%, , course: B. A YORÙBÁ, language: English, abstract: Èdè jẹ́ ọ̀nà kan tí à ń gbà bá ara wa sọ̀rọ̀. Ọpẹ́yẹmí (2015:21) ṣàlàyé pé èdè ni ariwo tí ó ti ẹnu àwa ènìyàn jáde tí ó ní ìtumọ̀, tí ó ní iṣẹ́ láti jẹ́ fún ẹni tí ó gbọ́ ọ, tí ó ní ìlànà kan pàtó tí àwọn elédè ń tẹ̀lé, tí ó sì jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà fún gbogbo àwọn olùsọ èdè náà. Èdè ni òpómúléró fún iṣẹ́ lítíréṣọ̀, láì sí èdè, kò lè sí àtiwáyé iṣẹ́ lítíréṣọ̀. Oríṣiríṣi ọ̀nà ni àwọn elédè ń gbà mú èdè wọn rẹwà yálà ní sísọ lẹ́nu tàbí nínú kíkọ sílẹ̀. Gbogbo àwọn èdè tó gbajú-gbajà ní àgbáyé bí Èdè Gẹ̀ẹ́sì, Faransé, Potogí, Lárúbáwá, Swàhílì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ló ní àwọn ọnà amédè-rẹwà fún afọ̀. Èyí kò sì yọ èdè Yorùbá sílẹ̀. Àwọn ìpèdè bẹ́ẹ̀ ni àwọn onímọ̀ pè ní àwọn “Ọnà-èdè", wọ́n sì máa ń mú kí afọ̀ Yorùbá kún fún ìmọ̀, ìtumọ̀ àti òye. Irúfẹ́ àwọn ìpèdè bẹ́ẹ̀ yàtọ̀ sí èdè ṣákálá tàbí àsọ̀jẹ ọ̀rọ̀ lásán. Àwọn ìpèdè yìí dúró gẹ́gẹ́ bí òpó fún afọ̀. Àwọn òpó wọ̀nyí ni àwọn Gẹ̀ẹ́sì pè ní “Figures of Speech”. Èyí fihàn pé gbogbo èdè ló ní tirẹ̀. Orúkọ tí èdè kọ̀ọ̀kan ń pe tirẹ̀ ló yàtọ̀. Ọnà-èdè ni àwọn hóró ọ̀rọ̀ tàbí àwọn ìpèdè tí aṣafọ̀ múlò láti mú adùn wọ afọ̀ rẹ̀, oríṣiríṣi sì ni àwọn ọnà-èdè tí a ní nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni òwe, àkanlò-èdè, àwítúnwí, àsọrégèé, ìfọ̀rọ̀dárà, ìfìrósínròjẹ, Ìbádọ́gba gbólóhùn, àfiwé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Kundenbewertungen

Schlagwörter

Okediji, Aja lo leru, Àkànlò èdè, Atoto Arere, Use of Language, Agbalagba Akan